AKOLE ORIN: "AYE MI, ORUN MI"
Orin Ojo Ibi Fun Aya Mi Owon, ododo eye mi.
Early morning sun is shining on your face
Aya mi owon, ololufe mi,Rukayat, Olabisi, Aweni
Ojo ibi re la wa yi,
Oju re lo n mu ayo wa mi,
Ife re dun ju oyin lo.
Happy birthday my darling, my omalicha wife
You are the center of my entire life
Happy Birthday ayomi, aye mi, Ife mi mother Opeyemi Adisa
Olorun yoo bukun fun e,
Iku omo, iku oko,
Ko ni je ti e lagbara Olorun.
Emi ni tire titi lae,
Ife mi fun e ko ni pare.
Aya mi omo Balogun
Look at the beauty, look at the style
You make the whole world stop with your smile
Mo gbadura fun e, ife mi,
Ki Olorun bu si ojo ori re,
Ki O je ki o pe, ki o dagba,
Ninu alafia ati ilera
Mother Oladimeji Atanda
Ki gbogbo aniyan okan re,
Ko di mimuse ni lagbara Allahurabi
Ibanuje ko ni sunmo ile wa,
Ayo re ko ni dinku laelae.
Happy birthday my darling, my omalicha wife
You are the center of my entire life
Happy Birthday ayomi, aye mi, Ife mi mother Opeyemi Adisa
Olorun yoo bukun fun e,
Iku omo, iku oko,
Ko ni je ti e lagbara Olorun.
Emi ni tire titi lae,
Ife mi fun e ko ni pare.
Aya mi omo Balogun
Ah ah, look at the way she glowing
See how the love is overflowing
Iwo ni obinrin ti mo feran,
Iya awon omo mi, Oluwajomiloju Abeo, Imran Adisa, Abdul Razak Atanda.
ore okan mi, Ife Oluwa temi ni kan
Laisi re, aye mi ko kun,
O seun fun ife re ti ko lopin.
Many more years I wish for you my dear
With nothing but happiness, nothing to fear
Hand in hand we walk this road of life
Ayo o ni fi o sile,
Ola ko ni fi o sile,
Ogo Olorun yoo ma ba o gbe ni gbagbo.
Amin.
Happy birthday my darling, my omalicha wife
You are the center of my entire life
Happy Birthday ayomi, aye mi, Ife mi mother Opeyemi Adisa
Olorun yoo bukun fun e,
Iku omo, iku oko,
Ko ni je ti e lagbara Olorun.
Emi ni tire titi lae,
Ife mi fun e ko ni pare.
Aya mi omo Balogun
Happy birthday, my queen
Best day that I’ve ever seen
We celebrate you, yes we do
Happy birthday to you
Chop life.
Happy Birthday, Ayami. Rukayat Olabisi Aweni omo Balogun
Mo feran e ju bi o ti ro lo!