Frobits
🎵 A song made on Frobits

Opin Aiye Ti De

San Tee Paramole Olanrewaju · 🇳🇬 Nigeria
0:000:00
Download Remix
Make your own song
Continues securely on the web
Lyrics

Mo tun ti de bimoshe de
Emi omo Olarewaju nanii
Oooooo eeeehhhh

Ojo ikeyin aye ti anpariwo,
Lojo to tipe, omatide oooo
Opin aiye ti de, bimoshe nde,
Irishi rishi ohun lonshele,
Ninu ile ati loode, ninu adugbo,
Ati lorile ede gbogbo,
Gbogbo ohun tonshe yii o je, ifunra

Oluwa o, opin aiye ti de,
Olorun mi, o daju pe o ti de,
Igbati aye nru, ti omi nse,
Baba, duro ti awa omo re,
Eseun Baba, fun aanu re,
Opin aiye ti de, sugbon a wa ninu re,

Amin opin aiye ni, ohun ti kosheleri,
Omamati nshele ninu aye,
Orile ede ti npara won,
Ogun itajesile ti poju,
Eyin to ifunra, kafi odidi enyan so oogun,
Tori owo, opin aiye ma ni,

Oluwa o, opin aiye ti de,
Olorun mi, o daju pe o ti de,
Igbati aye nru, ti omi nse,
Baba, duro ti awa omo re,
Eseun Baba, fun aanu re,
Opin aiye ti de, sugbon a wa ninu re,

Ki oloshelu ma para won nitori IPO,
Ojojumo ni eje eniyan nsho bi eeran ko,
Aiye ti yi pada, aiye ti doju ru,
Oluwa gba wa, Onye Ebube,
Ese o, Baba mi, owo re lo wa,

Ona kan mbe to daju,
Oruko Jesu ni abo wa,
Ninu iji, ninu iyan,
Oun nikan lo le gba wa la,
Olorun mi, duro ti wa,
Opin aiye ti de, sugbon a ki beru,

Oluwa o, opin aiye ti de,
Olorun mi, o daju pe o ti de,
Igbati aye nru, ti omi nse,
Baba, duro ti awa omo re,
Eseun Baba, fun aanu re,
Opin aiye ti de, sugbon a wa ninu re,

Opin aiye ti de, mo mo pe o mbo
Eseun Baba, Ese o, Olorun mi
Oluwa o, mumi de ile oloogo
Amen, Amen, Amen.

More songs by San Listen to songs created by others
FROBITS