[male
vocals]
[Intro] Emi
omo
Olarewaju
nanii
Oluwaseun,
a
dupe
fun
iye
[Verse 1] Kiku
mashe
pa
awon
ti
mo
fe
Kiku
mashe
pa
awon
to
femi
Emi
omo
Olarewaju
Kaye
ma
ba
mi
je,
Iye
ati
alaafia
ni
mo
n
tọrọ
Kiku
mashe
pa
awon
egbon
mi
Kiku
mashe
pa
awon
aburo
mi
Ojo
aayo
won
koshe
oju
mi
[Chorus] Iyami
ni
wura
mi,
mo
dupe
Babami
ni
dingi
mi,
mo
dupe
Oluwaseun
lo
lufemi ,
a
joke
Eni
ati
teni
ni
awon
omo
mi
Idunnu
won
lojojumo
lemi
n
fe
Ki
ibi
mashe
shele
siwon
Ohun
lemi
nbebe
hee
hee
Emi
omo
Olarewaju
kii
ndupe
[Verse 2] Ninu
aye
yi,
ola
ni
mo
nfe
Ki
omo
mi
dagba,
ko
tun
yin
mi
gbo
adura
mi
o ,
kii
lemope
wa
Gbogbo
ibi
ti
mo
ba
n
lo
Ki
owo
mi
te
ohun
rere
Ko
ma
she
si
wahala
ninu
ile
wa
Oluwa
pa
mi
mo
fun
awon
to
nfe
mi
[Chorus] Iyami
ni
wura
mi,
mo
dupe
Babami
ni
dingi
mi,
mo
dupe
Oluwaseun
lo
lufemi
o
Eni
ati
teni
ni
awon
omo
mi
Idunnu
won
lemi
n
fe
Emi
omo
Olarewaju
nanii
[Bridge] Ah
ah!
Omo
o!
Ojo
aayo
won
koshe
ojumi
Eru
o
ba
mi,
nitori
Oluwaseun
n
be
Olorun
to
toju
mi,
to
toju
idile
mi
Kiku
mashe
pa
awon
tonfemi
[Verse 3] Ojo
aayo
won
koshe
ojumi
Idunnu
won
lemi
n
fe
Emi
omo
Olarewaju
nanii
Mo
n
f’
ope
fun
Olorun
O
ti
seun,
O
ti
seun
[Chorus] Iyami
ni
wura
mi,
mo
dupe
Babami
ni
dingi
mi,
mo
dupe
Oluwaseun
lo
lufemi
o
Eniola
ati
teniniola
ni
awon
tonfemi
Idunnu
won
lemi
n
fe
Ki
oju
ma
ri
ibi
lorii
won
Emi
omo
Olarewaju
nanii
Emi
omo
Olarewaju
nanii
[Outro] Emi
omo
Olarewaju
nanii
Idunnu
won
lemi
n
fe
Oluwaseun
lo
lufemi
O
ti
seun,
o
ti
seun.