Emi omo Olarewaju nanii
Oluwaseun, a dupe fun iye
Kiku mashe pa awon ti mo fe
Kiku mashe pa awon to femi
Emi omo Olarewaju
Kaye ma ba mi je,
Iye ati alaafia ni mo n tọrọ
Kiku mashe pa awon egbon mi
Kiku mashe pa awon aburo mi
Ojo aayo won koshe oju mi
Iyami ni wura mi, mo dupe
Babami ni dingi mi, mo dupe
Oluwaseun lo lufemi , a joke
Eni ati teni ni awon omo mi
Idunnu won lojojumo lemi n fe
Ki ibi mashe shele siwon
Ohun lemi nbebe hee hee
Emi omo Olarewaju kii ndupe
Ninu aye yi, ola ni mo nfe
Ki omo mi dagba, ko tun yin mi
gbo adura mi o , kii lemope wa
Gbogbo ibi ti mo ba n lo
Ki owo mi te ohun rere
Ko ma she si wahala ninu ile wa
Oluwa pa mi mo fun awon to nfe mi
Iyami ni wura mi, mo dupe
Babami ni dingi mi, mo dupe
Oluwaseun lo lufemi o
Eni ati teni ni awon omo mi
Idunnu won lemi n fe
Emi omo Olarewaju nanii
Ah ah! Omo o!
Ojo aayo won koshe ojumi
Eru o ba mi, nitori Oluwaseun n be
Olorun to toju mi, to toju idile mi
Kiku mashe pa awon tonfemi
Ojo aayo won koshe ojumi
Idunnu won lemi n fe
Emi omo Olarewaju nanii
Mo n f’ope fun Olorun
O ti seun, O ti seun
Iyami ni wura mi, mo dupe
Babami ni dingi mi, mo dupe
Oluwaseun lo lufemi o
Eniola ati teniniola ni awon tonfemi
Idunnu won lemi n fe
Ki oju ma ri ibi lorii won
Emi omo Olarewaju nanii
Emi omo Olarewaju nanii
Idunnu won lemi n fe
Oluwaseun lo lufemi
O ti seun, o ti seun.